
Nigerian Afrobeat sensation Tolibian unveiled “Ramadan” produced by himself. Read the lyrics and sing along here.
[Chorus]
Saari, saari ti to Muslim ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
[Post-Chorus]
B’ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (Why, why, why)
B’ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Verse 1]
Awẹ tan, oju tajọsan
Awẹ tan, oju tajọsan
Irun ti to ki ẹ lọ bori
Saari ti to jẹ o, ah
Ẹ dide nilẹ o, ẹ lọ se jijẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ fi’gbo silẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ lo se jijẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ fi’gbo silẹ o
[Chorus]
Saari, saari ti to Muslim ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
[Post-Chorus]
B’ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (Why, why, why)
B’ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Verse 2]
Ẹ ye fa baki lọsan Ramadan
Ẹ ye gboloṣo lọsan Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu Ramadan
O ṣi tun wẹṣẹ ninu Ramadan
Subscribe to MX TV
Do you find Morexlusive useful? Click here to give us five stars rating!