Lyrics

Tolibian, ODUMODUBLVCK – Ramadan Kareem feat. BOJ (Official Lyrics)


Tolibian, ODUMODUBLVCK – Ramadan Kareem feat. BOJ (Official Lyrics)

Nigerian Afrobeat sensation Tolibian unveiled “Ramadan Kareem” featuring talented singers, ODUMODUBLVCK and Boj with production assistance from Ucee, Cross (Producer) & Greamar. Read the lyrics and sing along here.

[Chorus: Tolibian]
Saari, saari ti to Musulumi ẹ didé n’lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B’ọn gb’ounjẹ wa, mi o ni le jẹun
B’ọn gb’omi wa, mi o ni le mu o
Agba to l’omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Non-Lyrical vocals]

[Verse 1: Odumodublvck]
Black sheep forever, black sheep for life
Izgaaju ’til we kpeme, Antiworld gangsters
GE records, you get me? ODUMODUBLVCK
Kala
Musa serve me my saari suya
If that na where my niggas dey gather
If you think I’m fapping it, you’re right accordingly
[?]
When you been dey sisi, you dey jolly Ramadan Kareem (Opor)
[?]

[Verse 2: Tolibian]
L’ale Ramadan (Ehn)
[?]
L’ale Ramadan (Ehn)
Ibe la ti n ma ṣ’ere pa
L’ale Ramadan (Eyy)
Salam alaikum, wa alaikum assalam
E didé, e didé, e didé le

[Chorus: Tolibian]
Saari, saari ti to Musulumi ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B’ọn gb’ounjẹ wa mi o ni le jẹun
B’ọn gb’omi wa mi o ni le mu o
Agba to l’omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Non-Lyrcal vocals]

[Post-Chorus: Tolibian]
Ẹ ye fa baki lọsan Ramadan
Ẹ ye gb’oloṣo lọsan Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu Ramadan
O ṣi tun wẹ’ṣẹ ninu Ramadan

[Outro: Tolibian]
Yeah, yeah, yeah

Subscribe to MX TV

Do you find Morexlusive useful? Click here to give us five stars rating!

Leave a Comment