![Niniola – Ginger Me (Alum) [Official Lyrics]](https://morexlusive.com/wp-content/uploads/2025/05/Niniola-Ginger-Me-Alum-Official-Lyrics.jpeg)
Nigerian Afrobeat sensation Niniola has unveiled a new single titled “Ginger Me (Alum)” produced by Niphkeys. Read the lyrics and sing along here.
[Intro]
Pasero mi pe mi, o ni ki n…
Ki n ma rin..
Niphkeys
Nini de o eh
[Verse 1]
Pasero mi pe mi, oni ki n ma wo pata, kin ma bo
O ni ki n ma rin ṣara, o ni ki n wa pelu ọmọ kan
He ask me question, o ni ṣe mo ma ṣe threesome
I’ll do anything, ọmọ gidi ọmọ nla
[Refrain]
Ki inú re dun, ko dùn bi oyin
Cake e dun, kini re dùn ju oyin
Money plenty, make it rain on me daddy
Lo alum, lo alum, tó ba fẹ́ ko tight
[Chorus]
Ginger me, ginger me, ginger me my kopiko
Physical, physical, what I feel is physical
Ginger me, ginger me, ginger me my kopiko
Physical, physical, what I feel is physical
[Verse 2]
Lọ alum, lọ alum s’abé die, wa ri pe o ma tight
Lọ condom, lọ condom, ko ma d’oyún , ka ma gbọ́ story to touch
Ṣo’ra fun gonorrhea, to ba ti yun e, ko gbóná lo pharmacy
No pictures, no video, ko ma lo cast l’ori social media
Ayé lọ bá wa, ayé lo ba wa area sistеr
Ani ko ji je, ani ko ji je
[Refrain]
Ki inú re dun, ko dùn bi oyin
Cakе e dun, kini re dùn ju oyin
Money plenty, make it rain on me daddy (Make it rain)
Lo alum, lo alum, tó ba fẹ́ ko tight
Subscribe to MX TV
Do you find Morexlusive useful? Click here to give us five stars rating!